Lahillah (Live)-文本歌词

Lahillah (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Kòsí ohun tó le f’àjà sẹ́ níbi ká yin Muhammed

(Quranic recitation)

Aisha kòsí ohun tó le f’àjà sẹ́ níbi ká yin Muhammed

(Quranic recitation)

Kí ló wá lè fa ìjà sẹ́ níbi ká yin ba’lara

(Arabic recitation)

Kíni ohun tó le fàjà sẹ́ níbi ká yin Muhammad

(Arabic recitation)

Torí pé èyí o (ni Western Fújì o)

(Èyí o ni western Fújì)

Nana Aisha (nana Aisha)

Ṣẹ rí Gàjí, ó pàpà sọ ara ẹ̀ di manager stage

Nana Aisha (nana Aisha)

Aya t’Amuda Yusufu (ọmọ asabari)

Aisha aya Owólabí Yusuf, òun Aisha aya Amuda Asabari

Aisha wá di méjì (Arábámbí)

Òun aya Owólabí (aya Owólabí)

Amuda Yusufu (Owólabí)

Òun aya Amuda Yusufu (ọmọ asabari)

Aisha wá di méjì (ṣé ẹ rí nana)

Aya Amuda Yusufu (asabari)

Aisha (Aisha)

Bí mo ṣe ń ki Aisha méjèèjì ni Semiatu mi Basira Aríṣekọ́lá

Dodondawa

Balógun máa wolẹ̀ máa ràba o ṣeun

(Quranic recitation)

ìránṣẹ́ pé ànọ́bí ( lọ́sán kan òru kan)

Ó ti mu sá mọ̀ (pẹ̀lú ẹṣin ògo)

Bẹ́ẹ̀ ló ń pe Olúwa (Ọba alárànṣe)

Ó ń sọ pé Lahillah (Ọba Olúwa mi)

Ọ̀nà wo ni n ó gbà (tí ń fi dé ọ̀dọ̀ rẹ)

Ọba Ọlọ́run wá sì dáhùn (ìwọ anọbi mi)

(Arabic recitation)

Aríṣekọ́lá

Basira o káre (Aríṣekọ́lá)

Basiratu nílùú London (Aríṣekọ́lá)

Basiratu nílùú London (Aríṣekọ́lá)

Àríkẹ́ adé mi o (aríṣekọ́lá)

Basira Ọlọ́runtóyìn (Aríṣekọ́lá)

Basira Ọlọ́runtóyìn (Aríṣekọ́lá)

Àríkẹ́ adé mi (Aríṣekọ́lá)

Tí o bá dé London, ko bá mi tọ́jú ẹ̀lẹ̀ amin ní London (aríṣekọ́lá)

Àjọbí ọmọ mi ẹ̀lẹ̀ Amin ní London (aríṣekọ́lá)

Ọlọ́runtóyìn (aríṣekọ́lá)

Basira mama Faruku (aríṣekọ́lá)

Basira mama Faruku (aríṣekọ́lá)

Basiratu o (ah Basiratu o)

Tí n bá ń ba yín wí, ojú mi ni ẹ wò arábámbí

Bí n ṣe ń pè Semia Basiratu, Balógun wọlé

Dodondawa Balógun, Bidemi mi Abobo mi ńkọ́?

Bidemi, aruffy ruffy mi ẹlẹlẹtùrẹ́

O káre Rufai

Bidemi Rufai ọmọ máyọ̀délé

Máyọ̀délé nílùú Ìjẹ̀bú Òde, Bidemi Rufai

Kàmọ́rù àpò lo tún ń pawó sí

Bidemi mi Rufai