A mọ̀ yín o A mọ̀ yín o Àwa mọ̀ yín a tún yin mọ̀ o (Ẹ̀yin ti ń perí wa láìda gbogbo yín lẹ ó fara jẹgba) Ẹ̀yin tí ń perí wa láìda o A mọ̀ yín o A mọ̀ yín o Àwa mọ̀ yín a tún yin mọ̀ o (Ẹ̀yin ti ń perí wa láìda gbogbo yín lẹ ó fara jẹgba) Tabatiada fún abatẹnijẹ́ (Ẹ̀yin ti ń perí wa láìda gbogbo yín lẹ ó fara jẹgba) Abila’bi fún àwọn ọlọ̀tẹ̀ gbogbo yín lẹ ó fara jẹgba Àyìndé, ẹ̀yin tí ń perí wa láìda o A mọ̀ yín o A mọ̀ yín o Àwa mọ̀ yín a tún yin mọ̀ o (Ẹ̀yin ti ń perí wa láìda gbogbo yín lẹ ó fara jẹgba) Àyìndé mi Musiliu (egungun Ayédáadé) Ah! Tóyìn Ọya ò (Ọya o) Ọya ò (Ọya o) Òríìrì Ọya ò Ọya o (Ọya ò Ọya o) Ọya ò Ọya o (Ọya ò Ọya o) Modinatu o (Modinatu o) Ijó ọdún àdúrà la máa fi ṣe fúnra wa Mojísọ́lá to bá padà dé london K1 De Ultimate Naimotu ko máa ki Alhaja Naimotu bá n ki sílé Ní mo ní ó kú ọdún Ẹ̀mí ẹ̀ á ṣe púpọ̀ọ ẹ̀ ọdún láyé Ah! Musiliu mi (Musiliu mi) Àyìndé gbogbo oore Ọlọ́hun Ọba nínú ọdún yìí Ìtẹ́wọ́gbà níre ló máa jẹ Iwájú lojúgun ń gbé Àyìndé o ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn Ayédáadé Boma, gbogbo yín pátápátá mo ki yín ẹ kú ọdún Ẹ ṣọdún eléyìí, ẹ ó ṣe ẹ̀míì tọmọtọmọ Big London, iṣu ọmọ á jóná fún ẹ jẹ Ọlámilékan ọmọ Bismillahi nílùú Ọ̀yọ́ O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn gbogbo yín ni mo kí Musiliu mi (Musiliu mi) Mi ò mọ bí n ṣe máa dúpẹ́ tó ju àdúà lọ Àyìndé Abdulfatai ọmọ Ayọ̀ọlá iwájú lojúgun ń gbé O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn Gbogbo oore Ọlọ́hun Ọba ṣe fún ẹ kò ní bọ́ mọ́ ẹ lọ́wọ́ Wàá jẹ ẹ́, wàá láyọ̀ Ọmọ á jẹ ọmọ ọmọ á jẹ Ẹrù ẹ tó ti tò ò ní dojúrú Akin ọmọ Arógundádé Abdulwasiu kó o bá mi ki Wese mi (Wese mi) Ah! Àyìndé inú mi ó ń dùn (Wese mi) Inú mi ń dùn (Wese mi) Àrẹ̀mú ọmọ Ọláṣojú Ojúì í tère ojú ò ní tì ẹ bó w’ọlá Ọlọ́hun o (Wese mi) Ọlálékan Mọ́gàjí (Ọlálékan Mọ́gàjí) Èèyàn tó fojú di yín lọ béèrè ohun tó ṣeé Mi ò sọ̀rọ̀ o Nǹkan mẹ́ta ló pa pọ̀ arábámbí Ó pa’já, ó pà’jàpá ó tún p’òbúkọ dúdú Aì bá Lékan jà láì lówó ẹbọra ńlé Wese mi (Wese mi) Àyànlọlá mo ṣì ń bọ̀ ná lórí ọ̀rọ̀ tì ẹ àti Lékan Gaji Wese mi (Wese mi) Wasiu, Àjọkẹ́ ńkọ́? Ṣé ó ń bẹ l’álàáfíà ara sweetie Jọkẹ́ Wese mi (Wese mi) Abdulwasiu yí ó da fún ọ tí ọ́ pọ̀ (Wese mi) Òyìnbó elépo Mobil (Wese mi) Brother ló jẹ́ fún Jọkẹ́ baby mi (Wese mi) Abdulwasiu ẹ̀mí ẹ á ṣe púpọ̀ (Wese mi) Akin ọmọ Arógundádé mo kí ẹ kí ẹ o (Wese mi) Wasiu Àyìndé, ìsẹ̀yín ni inúù mí dùn (Adé orí ọ̀kín) Thank you Ètùtù yí ó gbowó iṣẹ́ yẹn (Adé orí ọ̀kín) O ṣé o Wese mi (wese mi) Kín ní yẹn máa ń wọ̀mí lára inú iṣan ló bọ́ sí K1 De Ultimate (Wese mi) Ah! òun làlùjó Wese (Adé orí ọ̀kín) Àwọn tó mọ ijó Wasiu jó kò sí Wàhálà (Wese mi) Kẹ̀kẹ́ Kẹ̀kẹ́ ni’jó mi (Wese mi) Àlùjó inú ẹ̀ ó pọ̀ (Wese mi) Ẹ wá máa tẹ le lórí fẹ́rẹ́fẹ́ Àfi ẹni tí ò bá mọ̀ ọ́ jó o ni òní bá mi jó Oṣé o Wese mi (Wese mi) Bá n kí Jọkẹ́ (bá n kí Jọkẹ́) Akin Arógundádé bá mi ṣe Ìtọ́jú Wasiu (Akin Arógundádé) Wasiu òyìnbó elépo (Wese mi)