ll Mesiko (Live)-文本歌词

ll Mesiko (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Ẹ̀bẹ̀ kan tí mò ń bẹ Ọba Àyìndé Adé Ọba má pa kádàrá ẹ dà s’áburú JẸ́JẸ́ Motors Ẹ ẹ̀ rí nǹkan, JẸ́JẸ́ MOTORS Àwọn bàbá tìwọ, wọ́n kọ́kọ́ ń ta motor láti kékeré K1 De Ultimate, JẸ́JẸ́ Iṣan ọrùn Ẹlẹlẹ, number 1 Iṣan ọrùn ọmọ Bello, Bello boys Àdúà ẹ ti gbà Ẹlẹlẹ Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá (Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá) Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá (Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá) Ẹlẹlẹ níṣẹ́ ni wọn ò mọ̀ Àyìndé Wasiu sọ fún wọn (Wọ́n tún ń na, wọ́n lówó le) Yeh! níṣẹ́ ni wọn ò mọ̀ Àyìndé Wasiu sọ fún wọn (Wọ́n tún ń na, wọ́n lówó le) Níṣe ni wọn ò mọ̀ Àyìndé Wasiu sọ fún wọn (Wọ́n tún ń na, wọ́n lówó le) Níṣẹ́ ni wọn ò mọ̀ Àyìndé Wasiu sọ fún wọn (Wọ́n tún ń na, wọ́n lówó le) Ẹlẹlẹ lọ́dún yìí owó tá a wí ti (Owó tá a wí ti dé) Owó tá a wí tí (Owó tá a wí ti dé) Ìlẹ̀kùn ọlà yìí ó ti ṣí finally (Owó tá a wí tí (Owó tá a wí ti dé) Kò ní tì lọ́lá Ọlọ́hun (Owó tá a wí ti dé) Ẹlẹlẹ àpamọ́wọ́ owó ẹ o (Owó tá a wí ti dé) Àpamọ́wọ́ owó ẹ (Owó tá a wí ti dé) Owó tó ní yẹn ò tíì tó, ọkọ Mosúnmọ́lá Púpọ̀ púpọ̀ púpọ̀ púpọ̀ púpọ̀ Ọlọ́hun bá mi fún ẹ (Owó tá a wí ti dé) Kò ì tíì tó Owó to ní yẹn kò ì tó o (máa pọ̀ si) Walahi (máa pọ̀ si) (Ó máa pọ̀ si) Kò ì tó o (ó máa pọ̀ si) Kò tíì tó (máa pọ̀ si) Kò tíì tó Kò ì tó o (ó máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) Kò ì tó o (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) (Kó máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) Kò ì tó o ( máa pọ̀ si) Number 1 (máa pọ̀ si) Kò ì tó o ( máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) Owó yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Owó yẹn kò ì tó (kó máa pọ̀ si) Kò tíì tó (máa pọ̀ si) Kò ì tíì tó (máa pọ̀ si) Owó yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Ah (máa pọ̀ si) Kò ì tó o ( máa pọ̀ si) Mi ò dénú, mi ò dénú (máa pọ̀ si) (Máa pọ̀ si) Kò ì tó o ( máa pọ̀ si) Owó yẹn kò ì tó (ó máa pọ̀ si) Owó yẹn kò ì tó (ó máa pọ̀ si) Ẹlẹlẹ owó to ní yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) (kó máa pọ̀ si) Kò ì tó o ( máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) Kò ì tó o ( máa pọ̀ si) O ò tíì ka nǹkankan fọ̀rọ́’lẹ̀ Èyí to ṣì máa kà láàárín oṣù kan sí èní Kọọ́lẹ̀, tó bá wá rí bẹ́ẹ̀ Owó yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) (kó máa pọ̀ si) kò ì tó o (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) Wọn ì tíì ra nǹkankan, wọ́n ṣì máa rà ju bẹ́ẹ̀ lọ Ẹlẹlẹ owó yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Owó yẹn kò ì tó (kó máa pọ̀ si) Bọ́lá owó yẹn kò ì tó (kó máa pọ̀ si) (Kó máa pọ̀ si) Ọdún Ọlọ́hun kò ì tó (máa pọ̀ si) Máa bọ̀ o (máa bọ̀ o) Máa bọ̀ o (máa bọ̀ o) Máa bọ̀ o (kó máa bọ̀ o) Máa bọ̀ o (máa bọ̀ o) Máa bọ̀ o (máa bọ̀ o) Máa bọ̀ o (máa bọ̀ o) Mo fẹ́ r’ọkọ̀ gidi (máa bọ̀ o) Mo fẹ́ r’ọkọ̀ gidi (kó máa bọ̀ o) Mo fẹ́ r’ọkọ̀ gidi ( máa bọ̀ o) Yàtọ̀ sí motor (máa bọ̀ o) Mo fẹ́ r’ọkọ̀ gidi ( máa bọ̀ o) Yàtọ̀ sí motor (kó máa bọ̀ o) Motor ọ̀tọ̀, ọkọ̀ ọ̀tọ̀, Car ọ̀tọ̀ Mo fẹ́ r’ọkọ̀ gidi (kó máa bọ̀ o) Mo fẹ́ r’ọkọ̀ gidi ( máa bọ̀ o) (Kó máa bọ̀ o) Ah (máa bọ̀ o) (máa bọ̀ o) (Kó máa bọ̀ o) Lamborghini yẹn kò ì tó o (máa bọ̀ o) Ah ah (máa bọ̀ o) (Kó máa bọ̀ o) (Máa bọ̀ o) irú ti burna yẹn, o ṣì máa ṣe púpọ̀ si (máa bọ̀ o) (Kó máa bọ̀ o) Ti Wizzy yẹn Kò ì tíì tó (máa bọ̀ o) Kiníyẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Kiníyẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) (máa pọ̀ si) (kó máa pọ̀ si) Ẹlẹlẹ kiní yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Kiní yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Irú ti burna yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Irú tí Wizzy wizzy yẹn kò ì tó (máa pọ̀ si) Ó ṣì máa padà wá o (máa bọ̀) Ah ah (máa bọ̀) Irú ti Ella (máa pọ̀ si) Ó ṣì máa pọ̀ si (máa pọ̀ si) Àánú Ọlọ́hun kò ì tó o (máa bọ̀) Bello Àánú Ọlọ́hun kò ì tó (máa bọ̀) Alawurabi kò wá ní yà yín lásìkò yìí báyìí Owó ni wọ́n fi ń ṣayé, ẹ ti ṣayé Àlàáfíà òhun ni oògùn ọrọ̀ téèyàn fi ń ṣe gbogbo ohun tó ṣe Ẹlẹlẹ, Ọlọ́hun Ọba ò ní fi àlàáfíà kò jí fi jẹ ẹ́ níyà Nínú Àlàáfíà nínú ọlá ńlá Torí pé o jẹ́ ọmọ kékeré O sì tún ní ìtẹríba ẹ ò ri bí? Owó ọkọ Mosúnmọ́lá O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn JẸ́JẸ́, o ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn Owó á máa ba yín gbé Soft ńkọ́? Amuda ńkọ́? Mr Soft Ihun t’Ọ́lọ́hun Ọba ṣe fún gbogbo yín kò ní bàjẹ́ Àmín Inspiration lẹ jẹ́ Ẹ̀yin gangan nì mọ́lẹ̀ àti ìtànná Gbogbo àwọn tó dẹ̀ kù, tí wọ́n ń ṣe dáadáa ní i yín Ọlọ́hun bá mi jẹ́ wọn Àmín o Bello, owó tí wọ́n fi ń ṣe ilé ayé Wàá ní, á pọ̀, á pọ̀, á pọ̀ Ó pọ̀ gan (ó pọ̀ gan) Ah! Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá (Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá) Wọn ò lè gbé’gẹ̀ (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Wọn ò lè gbé’gẹ̀ (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Wọn ò lè gbé’gẹ̀ (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Ẹ̀yin onísùúrù (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Òun l’Ọlọ́hun mi wà (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Bello, Ẹ̀yin onísùúrù (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Òun l’Ọlọ́hun mi wà (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Bellodox, Ẹ̀yin onísùúrù (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Òun l’Ọlọ́hun mi wà (wọn ò lè gbé’gẹ̀ si) Ẹlẹlẹ ó pọ̀ fún ẹ púpọ̀ (ó pọ̀ fun) Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá (Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá) Olúayé Fújì (Ọ̀gá wa o)